Enisungbalaja

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Compositor: Não Disponível

Orí ńṣaájò f'órí, k'órí k'ó lè ba sunwọn
Ọwọ ńṣaájò f'ọwọ, k'á r'óun tó dùn ṣe l'óde

Ló d'ífá fún ẹni sùn gbalaja, tó gb'ojú àlá w'ọjà
Èèló l'ẹ' ńtà'dùnnú? Eèló nì'bàlẹ' ọkàn?
Èèló l'ẹ' ńtà'lọsíwájú? Eèló l'ayọ'?

Ibi orí dá ni sí làágbé, kì ṣe ti ká jòkó tẹtẹrẹ
Ojú ayé a tàn roboto
Ọ'nà là f'ẹ'ni tí nṣè'bà èrò ọ'nà

Ló d'ífá fún ẹni sùn gbalaja, tó gb'ojú àlá w'ọjà
Èèló l'ẹ' ńtà'dùnnú? Eèló nì'bàlẹ' ọkàn?
Èèló l'ẹ' ntà'lọsíwájú? Eèló l'ayọ'?

Where is the sunshine (beyond the dark night?)
Where is the rain (beyond the drought?)
What lies beyond the bend (for the roaring river?)

Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ojú là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọjọ' là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọ'na là kedere o)

Ọjọ òní a p'ẹ'dá s'éré
Ọjọ àná l'àgbà o
Ọjọ ọ'la ń bọ' wá kánkán
Adùn f'ẹ'ni tó m'òye àsìkò

Ló d'ífá fún ẹni sùn gbalaja, tó gb'ojú àlá w'ọjà
Èèló l'ẹ' ń tà'dùnnú? Eèló nì'bàlẹ' ọkàn?
Èèló l'ẹ' ń tà'lọsíwájú? Eèló l'ayọ'?

Where is the sunshine (beyond the dark night?)
Where is the rain (beyond the drought?)
What lies beyond the bend (for the roaring river?)

Ọ'yẹ là, ọ'yẹ' là (ojú là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọjọ' là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọ'na là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ojú là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọjọ' là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọ'na là kedere o)

Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ojú là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọjọ' là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọ'na là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ojú là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọjọ' là kedere o)
Ọyẹ là, ọ'yẹ' là (ọ'na là kedere o)

©2003- 2025 lyrics.com.br · Aviso Legal · Política de Privacidade · Fale Conosco desenvolvido por Studio Sol Comunicação Digital