Ikore

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Compositor: Não Disponível

Ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹ kú àbò, ẹmá kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ

There is a season to be out in the fields
Many months of back-breaking labour
There is another season for bountiful harvest
And that is why we have gathered to celebrate, yea-yeah

Ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹ má kú àbò, ẹ kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ

Father was the knower who taught us everything
Mother was the pillar who gave us strength
All hands to the plough, we weathered many storms
And that is why we are happy to celebrate, yeah-e, ay-ay-ay

Ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹ kú àbò, ẹ má kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ
The drums are resounding, voices raised in song
Young maidens clapping, wiggling waists
I have only eyes for you, my sweet darling
You glow so bright in the moonlight, woah

Ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹ kú àbò, ẹ má kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ

Woah-oh, woah-oh
Ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹmà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹ kú àbò, ẹ má kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
K'ojú wá mà ri're àti ìdùnnú
K'ọwọ wá mà ko're ayọ
K'eti wá mà gbọ'ìròyìn aládùn
K'ilé wá mà ro f'ayọ

Heyy, ẹ mà wo'lẹ, ẹ mà wo'lẹ, ẹmà wo'lẹ o (ẹ mà wo'lẹ)
Ẹ kú àbò, ẹ má kú àbò, ẹ kú àbò
Ẹ mà rora, ọrẹ, àrà
Ẹní tí ń bọ' l'ókéré, a kí yín (ẹ kú àbò o)
Ẹní tí ń bẹ ni'joko a kí yín o (ẹ kú àbò o)
Ọdọ-'mọde pel'àgbàlagbà, a kí yín (ẹ kú àbò o)
Ah, Ìyá Ẹgbẹ', Bàbá Ètò, a má kí yín o (ẹ kú àbò o)
A kú ìjo, a má kú ayọ', a kí yìn (ẹ kú àbò o)
Ehn! Tẹ̀rín-tẹrìn pélọyaya, là kí yìn o (ẹ kú àbò o)
Ṣé bí ẹní s'ìṣẹ ye kò gbádùn, a ki yìn (ẹ kú àbò o)
Ko ní rè wá, Ẹgbẹ Aládùn, a ki yìn o (ẹ kú àbò o)
Gbogbo ìlú, a kú ayọ', a kí yín (ẹ kú àbò o)
Ah, ijo òní má tún yàtọ', a kí yín o (ẹ kú àbò o)
Eh, oh, a kí yín o (ẹ kú àbò o)
Oh, eh, a kí yín (ẹ kú àbò o)
(Ẹ kú àbò o)
(Ẹ kú àbò o)
(Ẹ kú àbò o)

©2003- 2025 lyrics.com.br · Aviso Legal · Política de Privacidade · Fale Conosco desenvolvido por Studio Sol Comunicação Digital