Iwure

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Compositor: Não Disponível

Sebi gbogbo eda lo n f'alafia
Gbogbo eda lo n fe'losiwaju
Ani gbogbo eda lo n fe'dunnu o
Ise owo won ni o je
Sebi gbogbo eda lo n fe'dera o
Gbogbo eda lo n fe ilera
Ani gbogbo eda lo n fe'tunu o
Ise owo won ni o je

Sebi gbogbo eda lo n f'alafia
Gbogbo eda lo n fe'losiwaju
Ani gbogbo eda lo n fe'dunnu o
Ise owo won ni o je
Sebi gbogbo eda lo n fe'dera o
Gbogbo eda lo nfe ilera
Ani gbogbo eda lo n fe'tunu o
Ise owo won ni o je

Ojo gbogbo lo dara f'onisuru
Igba gbogbo lo l'ayo fun asooto
Oun gbogbo lo derun f'afenifere
Osi o ni ba o n'ile yi o
Ofo o ni se o, ma wi pe, Ase o!

Ase o!
Ase o!

Ojo gbogbo lo dara f'onisuru
Igba gbogbo lo l'ayo fun asooto
Oun gbogbo lo derun f'afenifere
Osi o ni ba o n'ile yi o
Ofo o ni se o, ma wi pe Ase!
Ase!
Ase!

B'a ti wi beeni yi o ri
B'a ti wi beeni yi o ri o

B'a ti wi beeni yi o ri

B'a ti wi beeni yi o ri

©2003- 2025 lyrics.com.br · Aviso Legal · Política de Privacidade · Fale Conosco desenvolvido por Studio Sol Comunicação Digital