Lẹ́gẹ́lẹ́gẹ́

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Compositor: Não Disponível

L'ọjọ yẹn l'agbo o (l'agbo àjọdun)
Wọn n tẹ'lẹ pẹlu igboya (bi onile)
Wọn n fi t'ẹrìn t'ayọ ṣe po o (l'agbo idunnu)
Wọn o ba'ra wọn ja rara (rara o, rara o, rara o)

Wo wọn b'ọn ṣe n jo o e
Wo wọn b'ọn ṣe n kọ'rin ayọ
Wo wọn b'ọn ṣe n gb'ẹsẹ jẹjẹ
Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o
Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o
Ẹni ba wọn pe jo o (l'agbo àjọdun)
Ko le ṣá ii jo'jo yẹn o (ijo aláyọ)
Ọmọdé ma n bẹ níbẹ o (àwọn agba pẹlu)
Gbogbo wọn n ṣe pele o (jẹjẹ, jẹjẹ, jẹjẹ)

Wo wọn b'ọn ṣe n jo o e
Wo wọn b'ọn ṣe n kọ'rin ayọ
Wo wọn b'ọn ṣe n gb'ẹsẹ jẹjẹ
Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o
Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o
Wo wọn b'ọn ṣe n jo o e
Wo wọn b'ọn ṣe n kọ'rin ayọ
Wo wọn b'ọn ṣe n gb'ẹsẹ jẹjẹ
Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o
Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o

Amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o
Amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o
Àwọn ọmọ amilẹgẹlẹgẹ (amilẹgẹ)
Àwọn ọmọ alajọdun de o

©2003- 2025 lyrics.com.br · Aviso Legal · Política de Privacidade · Fale Conosco desenvolvido por Studio Sol Comunicação Digital