Omoniyun

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Compositor: Não Disponível

Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o
Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o

Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o
Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o

Ọmọ ní pe ní l'ọjà ayé
Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà
Ọmọ l'àwòrán eré o

Ọmọ ní pe ní l'ọjà ayé
Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà
Ọmọ l'àwòrán eré o

Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o

Mà yọ ṣẹ'ṣẹ'
(Bí à fún mí tọ) inú mí à dùn geere
Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà o
Ah, ṣébí kà tí r'ọmọ kẹ ní

Ma yo si
B'o ṣé l'obìnrin, ayọ rẹpẹtẹ
Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà o
Ṣébí kà tí rí kàn kẹ ní

Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o

Ọmọ ní pe ní l'ọjà ayé
Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà o
Ah, ọmọ l'àwòrán eré o
(Ọmọ níí wolé dé ni) ọmọ ní pe ní l'ọjà ayé
Ọmọniyun, ọmọnídè, ọmọ ní wúrà o
Ọmọ l'àwòrán eré o

Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o
Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o

Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o
Ọwọ mí òsì, ọwọ mí òtún
Ọwọ mí méjèèjì máa fí gb'ọmọ jó o

©2003- 2025 lyrics.com.br · Aviso Legal · Política de Privacidade · Fale Conosco desenvolvido por Studio Sol Comunicação Digital